Mase gbagbe mi
Jowo se ranti mi
Chorus
Ore Jowo mase gbagbe mi lojokojo nibikibi
Se ranti oro yii
Ore jowo mase gbagbe mi lojokojo nibikibi
Mase gbagbe mi
Verse 1
Ore to sunmo okan mi
Timo timo, ore to kamisi
O dami loju pe
Ore otito lo je
Oun toju wa ti jo ri
Ese e o de ye
So ranti b’ose pade mi?
Talo mo pe amaa soore titi?
Verse 2
Ore to se gbekele
Tooto to mo mi dele dele
O le pe k’oju ma kanra
Ma se jeki ojo meta yawa
Mo ranti ore ojo to se fun mi
Ore bi tie, ta lo le ri?
Verse 3
Oro yii wa latinu okan mi
Mo fe ko mo b’ose je simi
Ninu idunnu, ninu isoro
O duro timi bi aburo
Mo dupe o, modupe o
Modupe ooo
Adlib till fade