Iba re ni ma f’aiye mi ju
Sisin oo lemi a figba m ise
Shebi iyen nooni
Iyen gangan sha lo da mi fun
Eni aiye riaye to nigba mi o
Ogo f’oko re
Afuye gege ti o she gbe
Jigbin ni jigbin ni bi ate ileke
Kabiyesi mo se’ba re
Oba to ju gbogbo oba lo
Afuye gege ti o she gbe
Jigbin ni jigbin ni bi ate ileke
Kabiyesi mo se’ba re
Oba to ju gbogbo oba lo
Mo se’ba re o, mo se’ba re
Mo fori ba’le mo gbowo soke
Mo se’ba re o, mo se’ba re
Nirele okan mi mo wa ri
Kabiesi o mo se’ba re
Oba to ju gbogbo oba lo
Mo se’ba re o, mo se’ba re
Mo fori ba’le mo gbowo soke
Mo se’ba re o, mo se’ba re
Nirele okan mi mo wa ri
Kabiesi o mo se’ba re
Oba to ju gbogbo oba lo
Ta lo le so
Ta lo le ka won
Awon irawo t’owa loju orun
Egbe isiro le won
Ke so fun wa
Awon erupe inu okun
Tal o le so
Ta lo mo’ye
Ewa iseda toyi wa ka
Iyanu fun dudu
Iyanu fun fufun
Ose fe ni to gbon ati eni to go
Kaabiesi o mo se ba re o
Oba to ju gbogbo oba lo
Afuye gege ti o she gbe
Jigbin ni jigbin ni bi ate ileke
Kabiyesi mo se’ba re
Oba to ju gbogbo oba lo
Mo se’ba re o, mo se’ba re
Mo fori ba’le mo gbowo soke
Mo se’ba re o, mo se’ba re
Nirele okan mi mo wa ri
Kabiesi o mo se’ba re
Oba to ju gbogbo oba lo
Gbo gbo aye gbohun soke ni mu ewa won,
Won f’ogo fooko re
Ohun gbogbo fiyin fun o o
Iwo nikan l’oba t’ologo
Oju mi tiri
Eti mi ti gbo
Iyanu re yi aye ka
Mo gbo ninu eri awon eniyan mi mo
Mori ninu itan
Emi gangan nitan
Gbogbo ise re dadada ni
Aburu kankan o todo re wa
Ohun gbogbo lole yi pada
Sugbon rara tododo re ko
Kabiyesi o mo se’ba re o
Oba toju gbogbo oba lo e
Afuye gege ti o she gbe
Jigbin ni jigbin ni bi ate ileke
Kabiyesi mo se’ba re
Oba to ju gbogbo oba lo
Afuye gege mama se gbe
Okan mi pongbe mi mo si
Emi wao mo n wa o si oo hmm
Oba toju gbogbo oba lo
Ogo re yi aye ka
Emi se’ba, mo se’ba o
Mo fori ba’le ni waju ite aanu
Oba agbanilagbatan
Oba adani magbagbe eni
Mo wa ri
Emi se’ba re o oh oh oh
Oba to ju gbogbo oba lo hmm
Oba to ju gbogbo oba lo
Oba toju gbogbo oba lo sara re re o
Ehn kabiyesi mo se ba re o
Emi yi o ma fi bukun fun o lojojumo iwo nikan loni i
Ni gbogbo igba, ni gbogbo asiko, okan mi yio ma f’ogo f’okore
Oluwa orun ohun aiye ewa re yi aye ka, a n f’ogo f’okore hmm
Mo jewo mo jewo re, iwo nikan l’oluwa ko se lomiran leyin re
You are beautiful beyond description, ewa re koja ogbon ori
You are wonderful beyond comprehension, iyanu re koja oye