Intro
Ha….yeaaaa
E ribi 9ice ati KWAM ara ba nbi
If you wanna live long
If you wanna stay strong
Chorus (2x)
If you wanna live long and stay strong
Ile la loro (ile la loro)
Dokita a fun e ni imoran heh
Verse 1 – 9ice
Ogun ibile afun ni ni iwosan
Oloyun a bi were
Lai sise abe
Ewe nje, ogun nje (Kabiyesi o)
Ma se logun without doctor’s prescription
Mo n tenu mo
Mo n tenu mo
Call on doctor’s attention
If you need solution
Mo n tenu mo Adigun heh, mo n tenu mo
To much is given, much is asked of them
Ile a loro
Ile a loro
Repeat chorus (2x)
Verse 2 – KWAM 1
Iwosan ti de o
Alaboyun e mu ra o
Bo ba se pe eni ba e
Akinkoju a su
Alaboyun o ni ibi omiran to le lo
Ko ja si hospisitu
Tori pe ile la loro o
O se dada fun alaboyun sugbon
Ema se fi iwosan si ile
E o gbodo da ogun lo o
Lai se ase dokita o
Repeat chorus (2x)
Verse 3 – 9ice
Imo toto lo le segun arun gbogbo
Efan to gboro
Lo wa aran to lero
Ki eku ile gba ko so fun ti oko
Cleanliness is essential
Leads your life to potential
And the sound of times on your initial
Imo toto bori arun mo le
La se ni ka se itoju
Ka si fun alaboyun
Sheri alaboyun, kef o wo bowo o
Eja ka se itoju wa ni ayika wa
Repeat chorus (3x)